Share
  •  
  •  
  •  
  •  
  •  
  •  
  •  

Download Mp3 Bukola Joseph Hallelujah

Female Gospel singer, praise/worship leader and songwriter, Bukola Joseph releases a brand new single titled “Hallelujah”

Written and arranged by Bukola Joseph – “Hallelujah,” is a soul lifting song, and an expression of faith and thanksgiving delivered in an addictive African rhythm and sound.

Listen and Download Audio Below;

DOWNLOAD MP3: Bukola Joseph – Hallelujah

LYRICS: HALLELUJAH BY BUKOLA JOSEPH

Oluwa mo kepe O
Yara si odo mi
Feti si ohun mi mo be o
Nigbati moba nkepe o
Je ki adura mi wa sodo re
Kin le korin wipe allelujah Hallelujah x8

Nigbati mo wa ninu aye
Oju mi ri to laye
Mo kigbe pe o
olorun gba mi
Nigbati iji aye gbemilo
Iwo logba mi to ramipada
Ni mo wa korin wipe allelujah.
Hallelujah x8

Sanu fun mi olorun mi Sanu fun mi olugbala
Nitori okan mi kigbe pe o
Ni ojiji iye apare le mi o fise abo mi
Titi emi o fi ke allelujah.
Hallelujah x8

Hallelujah x8 Olorun sanu fun mi
Gegebi iseun ife re Gege bi ironu opo anu
Nu irekoja mi kuro
Ko si we mi ni awemo
Titi emi o fike hallelujah
Hallelujah x8

CONNECT:

Instagram: @bukolajoseph7

Facebook: @bukola j

Youtube: Bukola joseph

Leave a Reply